Ijoba Orun lere onigbagbo o
Ijoba Orun lere onigbagbo o
Ma je n kuna
Baba
Mumi dele o
Ma je n kuna,
Baba se
Mumi dele o
Owo ti mo ni ko le mumi dele o
Moto ti mo ri ra
Ko le wa mi de le o
Ore ti mo ni
Ko le sinmi de le o
Gbogbo iwe ti mo ri ka
Won o le gbe mi de le o
Ma je n kuna
Baba
Mumi de le o
Kin ma ku s'ajo bi efin
Mumi de le o
Aye l'oja
Orun nile
Mumi de le o
Aye l'oja
Orun nile see
Mumi dele o
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Ma ma je n kuna
Baba oooo
Baba oooo
Mumi dele o
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Mu mi dele o
(Dele, dele)
Ile ogo
Ile ayo
Ile ayo
Ile Alafia
Ile ogo
Ijoba Orun l'ere onigbagbo o
Ijoba Orun lere onigbagbo o
Ma je n kuna

Comments
Post a Comment