Ijoba Orun lere onigbagbo o Ijoba Orun lere onigbagbo o Ma je n kuna Baba Mumi dele o Ma je n kuna, Baba se Mumi dele o Owo ti mo ni ko le mumi dele o Moto ti mo ri ra Ko le wa mi de le o Ore ti mo ni Ko le sinmi de le o Gbogbo iwe ti mo ri ka Won o le gbe mi de le o Ma je n kuna Baba