Mo wo waju mi, mo ri owo Yin Mo w'eyin wo, mo ri ife Yin Won wa bere lo wo Mi pe bawo ni mo se se Mo so fun won wipe Emi naa ko o Olorun Oba ma ni Olorun Oba ma ni Olorun Oba ma ni Emi na ko o, Olorun Oba ma ni Olorun Oba ma ni Olorun Oba ma ni