You laid Your life oh Lord for my sake Jare gb'ope mi Daddy mo wa sope Receive my praise oh my Heavenly Father Onimajemu ayo Chorus: Tewo gb'ope mi Oluwa Baba mi O se Tewo gb'ope mi Oluwa Baba mi O se Opo nla to gbe ile Aye ro mo wa juba Re Tewo gb'ope mi Oluwa baba mi O se Giga giga ninu ola nla Atobijulo Tewo gb'ope mi Oluwa baba mi O se Tewo gb'ope mi Oluwa baba mi O se