Hmmmm Omo eniyan F'eti si Oro agba, bi o se l'owuro A se lojo ale Verse I Bowu ko pe titi Iya aye wa o n bo wa d'opin Aimola eda lo mu eda s'aniyan ola Olorun ti seleri, oro Baba ko ni ye Ainigbagba lo mu eda r'aropin Bi okun n fo Ti osa n sa Otito wa laaye Igbagbo ni orisun ohun gbogbo Chorus Oh huu huuu aye yi ko male Aye ole f'eni to nigbagbo p'aye ole Oh huu huuu aye yi ko male Aye ole f'eni to nigbagbo p'aye ole Oh huu huuu aye yi ko male Aye ole f'eni to nigbagbo p'aye ole Oh huu huuu aye yi ko male Aye ole f'eni to nigbagbo p'aye ole